Ẹ nlẹ́ ń bẹ̀un, ẹ káàbọ̀ s'órí ìkànì Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ Radio, níbi tí a ó ti máa fi àwọn ètò lórí àṣà, ìmọ̀, ìtàn àti ìṣe Yorùbá dá kọnkọ-lúkọ láti lè máa gbé èdè Yorùbá lárugẹ lórí afẹ́fẹ́. Igbadun yín lórí afẹ́fẹ́ ni radio yí wà fún . Ẹ máa báwa bọ̀. Ẹ ṣeun púpọ̀.